46 “‘Èyí ni òfin tó wà nípa àwọn ẹranko, àwọn ẹ̀dá tó ń fò, gbogbo ohun alààyè tó wà nínú omi àti gbogbo ẹ̀dá tó ń gbá yìn-ìn ní ayé, 47 láti fi ìyàtọ̀ sáàárín èyí tí kò mọ́ àti èyí tó mọ́, sáàárín àwọn ohun alààyè tí ẹ lè jẹ àti àwọn tí ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ.’”+