-
Àìsáyà 62:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Mo ti yan àwọn olùṣọ́ sórí àwọn ògiri rẹ, ìwọ Jerúsálẹ́mù.
Nígbà gbogbo, láti àárọ̀ ṣúlẹ̀ àti ní gbogbo òru mọ́jú, wọn ò gbọ́dọ̀ dákẹ́.
Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń sọ̀rọ̀ Jèhófà,
Ẹ má sinmi,
-
Jeremáyà 6:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Àmọ́ wọ́n sọ pé: “A ò ní fetí sí i.”+
-
-
-