-
Ìsíkíẹ́lì 23:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Wọ́n di aṣẹ́wó ní Íjíbítì;+ láti kékeré ni wọ́n ti ń ṣe aṣẹ́wó. Wọ́n tẹ ọmú wọn níbẹ̀, wọ́n sì fọwọ́ pa wọ́n láyà nígbà tí wọn ò tíì mọ ọkùnrin.
-