Ìsíkíẹ́lì 23:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Orúkọ ẹ̀gbọ́n ni Òhólà,* orúkọ àbúrò rẹ̀ sì ni Òhólíbà.* Wọ́n di tèmi, wọ́n sì bí àwọn ọmọ ọkùnrin àti obìnrin. Èyí tó ń jẹ́ Òhólà ni Samáríà,+ èyí tó sì ń jẹ́ Òhólíbà ni Jerúsálẹ́mù.
4 Orúkọ ẹ̀gbọ́n ni Òhólà,* orúkọ àbúrò rẹ̀ sì ni Òhólíbà.* Wọ́n di tèmi, wọ́n sì bí àwọn ọmọ ọkùnrin àti obìnrin. Èyí tó ń jẹ́ Òhólà ni Samáríà,+ èyí tó sì ń jẹ́ Òhólíbà ni Jerúsálẹ́mù.