Àìsáyà 65:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àmọ́ ẹ wà lára àwọn tó ń fi Jèhófà sílẹ̀,+Àwọn tó ń gbàgbé òkè mímọ́ mi,+Àwọn tó ń tẹ́ tábìlì fún ọlọ́run OríireÀti àwọn tó ń bu àdàlù wáìnì kún inú ife fún ọlọ́run Àyànmọ́.
11 Àmọ́ ẹ wà lára àwọn tó ń fi Jèhófà sílẹ̀,+Àwọn tó ń gbàgbé òkè mímọ́ mi,+Àwọn tó ń tẹ́ tábìlì fún ọlọ́run OríireÀti àwọn tó ń bu àdàlù wáìnì kún inú ife fún ọlọ́run Àyànmọ́.