Ìsíkíẹ́lì 33:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nígbà tó yá, ní ọjọ́ karùn-ún, oṣù kẹwàá, ọdún kejìlá tí a ti wà ní ìgbèkùn, ọkùnrin kan tó sá àsálà kúrò ní Jerúsálẹ́mù wá bá mi,+ ó sì sọ pé: “Wọ́n ti pa ìlú náà run!”+
21 Nígbà tó yá, ní ọjọ́ karùn-ún, oṣù kẹwàá, ọdún kejìlá tí a ti wà ní ìgbèkùn, ọkùnrin kan tó sá àsálà kúrò ní Jerúsálẹ́mù wá bá mi,+ ó sì sọ pé: “Wọ́n ti pa ìlú náà run!”+