-
Ìsíkíẹ́lì 3:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Màá sì mú kí ahọ́n rẹ lẹ̀ mọ́ òkè ẹnu rẹ, o ò ní lè sọ̀rọ̀, o ò sì ní lè bá wọn wí, torí ọlọ̀tẹ̀ ilé ni wọ́n.
-
-
Ìsíkíẹ́lì 33:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Àmọ́ ní alẹ́ tó ṣáájú ọjọ́ tí ọkùnrin tó sá àsálà náà wá, ọwọ́ Jèhófà wá sára mi, ó sì ti la ẹnu mi kí ọkùnrin náà tó wá bá mi ní àárọ̀. Ẹnu mi wá là, mi ò sì yadi mọ́.+
-