-
Ìsíkíẹ́lì 21:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 “Ìwọ ọmọ èèyàn, sọ tẹ́lẹ̀, kí o sì sọ pé, ‘Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nípa àwọn ọmọ Ámónì àti nípa ẹ̀gàn wọn nìyí.’ Sọ pé, ‘Idà! Wọ́n ti fa idà yọ láti fi pa wọ́n; wọ́n ti dán an kó lè jẹ nǹkan run, kó sì lè máa kọ mànà.
-
-
Ìsíkíẹ́lì 21:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Wọ́n á fi ọ́ dáná;+ wọ́n á ta ẹ̀jẹ̀ rẹ sílẹ̀ ní ilẹ̀ náà, wọn ò sì ní rántí rẹ mọ́, torí èmi Jèhófà ti sọ̀rọ̀.’”
-