ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìsíkíẹ́lì 2:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Nígbà tó bá mi sọ̀rọ̀, ẹ̀mí wọ inú mi, ó sì mú kí n dìde dúró+ kí n lè gbọ́ ọ̀rọ̀ Ẹni tó ń bá mi sọ̀rọ̀.

  • Dáníẹ́lì 10:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Lẹ́yìn náà, ó sọ pé: “Má bẹ̀rù,+ ìwọ ọkùnrin tó ṣeyebíye gan-an.*+ Kí o ní àlàáfíà.+ Jẹ́ alágbára, àní kí o jẹ́ alágbára.” Bó ṣe ń bá mi sọ̀rọ̀, mo lókun, mo sì sọ pé: “Kí olúwa mi sọ̀rọ̀, torí o ti fún mi lókun.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́