Ìsíkíẹ́lì 27:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 O ti wá dákẹ́ sínú agbami òkun, sínú ibú omi,+Ìwọ àti gbogbo ọjà rẹ àti àwọn èèyàn rẹ ti rì sínú òkun.+
34 O ti wá dákẹ́ sínú agbami òkun, sínú ibú omi,+Ìwọ àti gbogbo ọjà rẹ àti àwọn èèyàn rẹ ti rì sínú òkun.+