Ìsíkíẹ́lì 26:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Wọ́n á kọ orin arò*+ torí rẹ, wọ́n á sì sọ fún ọ pé: “Wo bí o ti ṣègbé,+ ìwọ tí àwọn tó wá láti òkun ń gbé inú rẹ̀, ìwọ ìlú tí wọ́n ń yìn;Ìwọ àti àwọn* tó ń gbé inú rẹ jẹ́ alágbára lórí òkun,+Ẹ sì ń dẹ́rù ba gbogbo àwọn tó ń gbé ayé!
17 Wọ́n á kọ orin arò*+ torí rẹ, wọ́n á sì sọ fún ọ pé: “Wo bí o ti ṣègbé,+ ìwọ tí àwọn tó wá láti òkun ń gbé inú rẹ̀, ìwọ ìlú tí wọ́n ń yìn;Ìwọ àti àwọn* tó ń gbé inú rẹ jẹ́ alágbára lórí òkun,+Ẹ sì ń dẹ́rù ba gbogbo àwọn tó ń gbé ayé!