Jóṣúà 13:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn ilẹ̀ tó ṣẹ́ kù nìyí:+ gbogbo ilẹ̀ àwọn Filísínì àti ti gbogbo àwọn ará Géṣúrì+ Jóṣúà 13:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 ilẹ̀ àwọn ará Gébálì+ àti gbogbo Lẹ́bánónì lápá ìlà oòrùn, láti Baali-gádì ní ìsàlẹ̀ Òkè Hámónì títí dé Lebo-hámátì;*+
5 ilẹ̀ àwọn ará Gébálì+ àti gbogbo Lẹ́bánónì lápá ìlà oòrùn, láti Baali-gádì ní ìsàlẹ̀ Òkè Hámónì títí dé Lebo-hámátì;*+