-
Àwọn Onídàájọ́ 11:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Ó pa wọ́n lọ rẹpẹtẹ láti Áróérì títí dé Mínítì, ogún (20) ìlú, títí lọ dé Ebẹli-kérámímù. Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe ṣẹ́gun àwọn ọmọ Ámónì nìyẹn.
-