Ìsíkíẹ́lì 26:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Yóò di ibi tí wọ́n ń sá àwọ̀n sí láàárín òkun.’+ “‘Torí èmi fúnra mi ti sọ̀rọ̀,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí, ‘àwọn orílẹ̀-èdè yóò sì kó o ní ẹrù.
5 Yóò di ibi tí wọ́n ń sá àwọ̀n sí láàárín òkun.’+ “‘Torí èmi fúnra mi ti sọ̀rọ̀,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí, ‘àwọn orílẹ̀-èdè yóò sì kó o ní ẹrù.