Dáníẹ́lì 2:48 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Ọba wá gbé Dáníẹ́lì ga, ó fún un ní ọ̀pọ̀ ẹ̀bùn tó dáa, ó sì fi ṣe alákòóso lórí gbogbo ìpínlẹ̀* Bábílónì+ àti olórí àwọn aṣíwájú gbogbo amòye Bábílónì.
48 Ọba wá gbé Dáníẹ́lì ga, ó fún un ní ọ̀pọ̀ ẹ̀bùn tó dáa, ó sì fi ṣe alákòóso lórí gbogbo ìpínlẹ̀* Bábílónì+ àti olórí àwọn aṣíwájú gbogbo amòye Bábílónì.