-
Ìsíkíẹ́lì 27:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Édómù bá ọ dòwò pọ̀ torí ọjà rẹ pọ̀ gan-an. Òkúta tọ́kọ́wásì, òwú aláwọ̀ pọ́pù, aṣọ tí wọ́n kóṣẹ́ aláràbarà sí, aṣọ àtàtà, iyùn àti òkúta rúbì ni wọ́n fi ṣe pàṣípààrọ̀ ọjà lọ́dọ̀ rẹ.
-