Ìsíkíẹ́lì 27:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Gbogbo àwọn tó ń gbé ní àwọn erékùṣù yóò wò ọ́ tìyanutìyanu,+Ìbẹ̀rù yóò mú kí jìnnìjìnnì bá àwọn ọba wọn,+ ìdààmú yóò sì hàn lójú wọn.
35 Gbogbo àwọn tó ń gbé ní àwọn erékùṣù yóò wò ọ́ tìyanutìyanu,+Ìbẹ̀rù yóò mú kí jìnnìjìnnì bá àwọn ọba wọn,+ ìdààmú yóò sì hàn lójú wọn.