Àìsáyà 32:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ibi tí àlàáfíà ti jọba làwọn èèyàn mi á máa gbé,Nínú àwọn ibi tó ní ààbò àtàwọn ibi ìsinmi tó pa rọ́rọ́.+ Jeremáyà 23:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Júdà máa rí ìgbàlà ní ìgbà ayé rẹ̀,+ Ísírẹ́lì sì máa wà ní ààbò.+ Orúkọ tí a ó sì máa pè é ni, Jèhófà Ni Òdodo Wa.”+ Hósíà 2:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ní ọjọ́ yẹn, màá bá àwọn ẹran inú igbó dá májẹ̀mú nítorí wọn,+Màá sì bá àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run àti ohun tó ń rákò lórí ilẹ̀ dá májẹ̀mú;+Màá mú ọfà* àti idà àti ogun kúrò ní ilẹ̀ náà,+Màá sì jẹ́ kí wọ́n dùbúlẹ̀* ní ààbò.+
18 Ibi tí àlàáfíà ti jọba làwọn èèyàn mi á máa gbé,Nínú àwọn ibi tó ní ààbò àtàwọn ibi ìsinmi tó pa rọ́rọ́.+
6 Júdà máa rí ìgbàlà ní ìgbà ayé rẹ̀,+ Ísírẹ́lì sì máa wà ní ààbò.+ Orúkọ tí a ó sì máa pè é ni, Jèhófà Ni Òdodo Wa.”+
18 Ní ọjọ́ yẹn, màá bá àwọn ẹran inú igbó dá májẹ̀mú nítorí wọn,+Màá sì bá àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run àti ohun tó ń rákò lórí ilẹ̀ dá májẹ̀mú;+Màá mú ọfà* àti idà àti ogun kúrò ní ilẹ̀ náà,+Màá sì jẹ́ kí wọ́n dùbúlẹ̀* ní ààbò.+