-
Jeremáyà 25:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 “‘Àwọn tí Jèhófà máa pa ní ọjọ́ yẹn máa pọ̀ láti ìkángun kan ayé títí dé ìkángun kejì. A ò ní ṣọ̀fọ̀ wọn, a ò ní kó wọn jọ, bẹ́ẹ̀ ni a ò ní sin wọ́n. Wọ́n á dà bí ajílẹ̀ lórí ilẹ̀.’
-