-
Ìsíkíẹ́lì 30:9, 10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ní ọjọ́ yẹn, èmi yóò rán àwọn òjíṣẹ́ nínú àwọn ọkọ̀ òkun, kí wọ́n lè mú kí Etiópíà tó dá ara rẹ̀ lójú gbọ̀n rìrì; ẹ̀rù yóò bà wọ́n ní ọjọ́ ìdájọ́ tó ń bọ̀ wá sórí Íjíbítì, torí ó dájú pé ó máa dé.’
10 “Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Èmi yóò mú kí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì pa ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ àwọn ará Íjíbítì run.+
-