Náhúmù 3:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ṣé o sàn ju No-ámónì* lọ,+ tó jókòó sí ẹ̀gbẹ́ ipa odò Náílì?+ Omi ló yí i ká;Òkun ni ọrọ̀ rẹ̀, òkun sì ni ògiri rẹ̀. 9 Etiópíà àti Íjíbítì ló fún un ní agbára tí kò láàlà. Pútì+ àti àwọn ará Líbíà sì ni olùrànlọ́wọ́ rẹ̀.+
8 Ṣé o sàn ju No-ámónì* lọ,+ tó jókòó sí ẹ̀gbẹ́ ipa odò Náílì?+ Omi ló yí i ká;Òkun ni ọrọ̀ rẹ̀, òkun sì ni ògiri rẹ̀. 9 Etiópíà àti Íjíbítì ló fún un ní agbára tí kò láàlà. Pútì+ àti àwọn ará Líbíà sì ni olùrànlọ́wọ́ rẹ̀.+