ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 46:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Íjíbítì dà bí abo ọmọ màlúù tó lẹ́wà,

      Àmọ́ kòkòrò tó ń tani máa wá bá a láti àríwá.

  • Ìsíkíẹ́lì 31:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 “‘Igi wo ní Édẹ́nì ló ní ògo tó sì lágbára bíi tìrẹ?+ Àmọ́, ó dájú pé ìwọ àti àwọn igi Édẹ́nì yóò lọ sínú ilẹ̀ tó wà nísàlẹ̀. Àárín àwọn aláìdádọ̀dọ́* ni wàá dùbúlẹ̀ sí, pẹ̀lú àwọn tí wọ́n fi idà pa. Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí Fáráò àti gbogbo èèyàn rẹ̀ nìyí,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́