-
Ìsíkíẹ́lì 32:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 “Ọmọ èèyàn, pohùn réré ẹkún torí àwọn ará Íjíbítì tí wọ́n pọ̀ rẹpẹtẹ, kí o sì mú un lọ sí ilẹ̀ tó wà nísàlẹ̀, òun àti àwọn ọmọbìnrin àwọn orílẹ̀-èdè tó lágbára, pẹ̀lú àwọn tó ń lọ sínú kòtò.*
-
-
Ìsíkíẹ́lì 32:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 “‘Wọ́n á ṣubú sí àárín àwọn tí wọ́n fi idà pa.+ Wọ́n ti fà á lé idà lọ́wọ́; ẹ wọ́ ọ lọ, pẹ̀lú gbogbo èèyàn rẹ̀ tó pọ̀ rẹpẹtẹ.
-