-
Ìsíkíẹ́lì 32:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 “‘Fáráò yóò rí gbogbo nǹkan yìí, gbogbo ohun tó ṣẹlẹ̀ sí ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èèyàn rẹ̀ yóò sì tù ú nínú;+ wọn yóò fi idà pa Fáráò àti gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.
-