Ìsíkíẹ́lì 30:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Èmi yóò sọ àwọn omi tó ń ṣàn láti odò Náílì+ di ilẹ̀ gbígbẹ, èmi yóò sì ta ilẹ̀ náà fún àwọn èèyàn burúkú. Màá mú kí àwọn àjèjì sọ ilẹ̀ náà àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀ di ahoro.+ Èmi Jèhófà ti sọ̀rọ̀.’
12 Èmi yóò sọ àwọn omi tó ń ṣàn láti odò Náílì+ di ilẹ̀ gbígbẹ, èmi yóò sì ta ilẹ̀ náà fún àwọn èèyàn burúkú. Màá mú kí àwọn àjèjì sọ ilẹ̀ náà àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀ di ahoro.+ Èmi Jèhófà ti sọ̀rọ̀.’