-
Ìsíkíẹ́lì 30:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Màá sì tú àwọn ará Íjíbítì ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè, màá fọ́n wọn ká sí àwọn ilẹ̀,+ wọn yóò sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.’”
-