Ìsíkíẹ́lì 37:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ó wá sọ fún mi pé: “Ọmọ èèyàn, gbogbo ilé Ísírẹ́lì ni àwọn egungun yìí.+ Wọ́n ń sọ pé, ‘Egungun wa ti gbẹ, a ò sì ní ìrètí mọ́.+ Wọ́n ti pa wá run pátápátá.’
11 Ó wá sọ fún mi pé: “Ọmọ èèyàn, gbogbo ilé Ísírẹ́lì ni àwọn egungun yìí.+ Wọ́n ń sọ pé, ‘Egungun wa ti gbẹ, a ò sì ní ìrètí mọ́.+ Wọ́n ti pa wá run pátápátá.’