Àìsáyà 31:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Ẹ pa dà sọ́dọ̀ Ẹni tí ẹ fi àfojúdi ṣọ̀tẹ̀ sí, ẹ̀yin èèyàn Ísírẹ́lì.+ Lúùkù 15:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Mò ń sọ fún yín pé, lọ́nà kan náà, àwọn áńgẹ́lì Ọlọ́run máa ń yọ̀ torí ẹlẹ́ṣẹ̀ kan tó ronú pìwà dà.”+
10 Mò ń sọ fún yín pé, lọ́nà kan náà, àwọn áńgẹ́lì Ọlọ́run máa ń yọ̀ torí ẹlẹ́ṣẹ̀ kan tó ronú pìwà dà.”+