20 Àmọ́ tí olódodo bá fi òdodo tó ń ṣe sílẹ̀, tó sì wá ń ṣe ohun tí kò dáa, èmi yóò fi ohun ìkọ̀sẹ̀ síwájú rẹ̀, yóò sì kú.+ Tí ìwọ kò bá kìlọ̀ fún un, yóò kú torí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, mi ò sì ní rántí iṣẹ́ òdodo tó ti ṣe, àmọ́ ọwọ́ rẹ ni màá ti béèrè ẹ̀jẹ̀ rẹ̀.+