Ẹ́kísódù 22:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 “Tí o bá gba aṣọ ọmọnìkejì rẹ láti fi ṣe ìdúró,*+ kí o dá a pa dà fún un nígbà tí oòrùn bá wọ̀.