Àìsáyà 40:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ó máa bójú tó* agbo ẹran rẹ̀ bíi ti olùṣọ́ àgùntàn.+ Ó máa fi apá rẹ̀ kó àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn jọ,Ó sì máa gbé wọn sí àyà rẹ̀. Ó máa rọra da àwọn tó ń fọ́mọ lọ́mú.+ Jòhánù 21:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Lẹ́yìn tí wọ́n jẹ oúnjẹ àárọ̀ tán, Jésù sọ fún Símónì Pétérù pé: “Símónì ọmọ Jòhánù, ṣé o nífẹ̀ẹ́ mi ju ìwọ̀nyí lọ?” Ó sọ fún un pé: “Bẹ́ẹ̀ ni, Olúwa, o mọ̀ pé mo ní ìfẹ́ tó jinlẹ̀ fún ọ.” Ó sọ fún un pé: “Máa bọ́ àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn mi.”+
11 Ó máa bójú tó* agbo ẹran rẹ̀ bíi ti olùṣọ́ àgùntàn.+ Ó máa fi apá rẹ̀ kó àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn jọ,Ó sì máa gbé wọn sí àyà rẹ̀. Ó máa rọra da àwọn tó ń fọ́mọ lọ́mú.+
15 Lẹ́yìn tí wọ́n jẹ oúnjẹ àárọ̀ tán, Jésù sọ fún Símónì Pétérù pé: “Símónì ọmọ Jòhánù, ṣé o nífẹ̀ẹ́ mi ju ìwọ̀nyí lọ?” Ó sọ fún un pé: “Bẹ́ẹ̀ ni, Olúwa, o mọ̀ pé mo ní ìfẹ́ tó jinlẹ̀ fún ọ.” Ó sọ fún un pé: “Máa bọ́ àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn mi.”+