ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 23:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Torí náà, ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ sí àwọn olùṣọ́ àgùntàn tó ń bójú tó àwọn èèyàn mi nìyí: “Ẹ ti tú àwọn àgùntàn mi ká, ẹ sì ń fọ́n wọn ká ṣáá, ẹ kò sì tọ́jú wọn.”+

      “Torí náà màá fìyà jẹ yín nítorí ìwà ibi yín,” ni Jèhófà wí.

  • Jeremáyà 50:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Àwọn èèyàn mi ti di agbo àgùntàn tó sọ nù.+ Àwọn olùṣọ́ àgùntàn wọn ti kó wọn ṣìnà.+ Wọ́n dà wọ́n lọ sórí àwọn òkè ńlá, wọ́n ń rìn látorí òkè ńlá dórí òkè kékeré. Wọ́n ti gbàgbé ibi ìsinmi wọn.

  • Mátíù 9:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Nígbà tó rí àwọn èrò, àánú wọn ṣe é,+ torí wọ́n dà bí àgùntàn tí a bó láwọ, tí a sì fọ́n ká láìní olùṣọ́ àgùntàn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́