-
Ìsíkíẹ́lì 16:46, 47Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
46 “‘Samáríà ni ẹ̀gbọ́n rẹ obìnrin,+ tí òun àti àwọn ọmọ rẹ̀ obìnrin* ń gbé ní àríwá rẹ.*+ Sódómù+ sì ni àbúrò rẹ obìnrin, tí òun àti àwọn ọmọ rẹ̀ obìnrin ń gbé ní gúúsù rẹ.*+ 47 Kì í ṣe pé o rìn ní ọ̀nà wọn, tí o sì bá wọn ṣe àwọn ohun ìríra wọn nìkan ni, àmọ́ láàárín àkókò díẹ̀, ìwà ìbàjẹ́ tí ò ń hù nínú gbogbo iṣẹ́ rẹ burú ju tiwọn lọ.+
-