Àìsáyà 14:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 O sọ lọ́kàn rẹ pé, ‘Màá gòkè lọ sí ọ̀run.+ Màá gbé ìtẹ́ mi ga ju àwọn ìràwọ̀ Ọlọ́run,+Màá sì jókòó sórí òkè ìpàdé,Láwọn ibi tó jìnnà jù ní àríwá.+ 14 Màá gòkè lọ sórí àwọsánmà;*Màá mú ara mi jọ Ẹni Gíga Jù Lọ.’
13 O sọ lọ́kàn rẹ pé, ‘Màá gòkè lọ sí ọ̀run.+ Màá gbé ìtẹ́ mi ga ju àwọn ìràwọ̀ Ọlọ́run,+Màá sì jókòó sórí òkè ìpàdé,Láwọn ibi tó jìnnà jù ní àríwá.+ 14 Màá gòkè lọ sórí àwọsánmà;*Màá mú ara mi jọ Ẹni Gíga Jù Lọ.’