Dáníẹ́lì 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “‘Bí mo ṣe ń wo ìran tí mo rí nígbà tí mo wà lórí ibùsùn mi, mo rí olùṣọ́ kan, ẹni mímọ́, tó ń sọ̀ kalẹ̀ láti ọ̀run.+ Dáníẹ́lì 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mo gbọ́ tí ẹni mímọ́ kan ń sọ̀rọ̀, ẹni mímọ́ míì sì sọ fún ẹni tó ń sọ̀rọ̀ pé: “Báwo ni ìran ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nígbà gbogbo* àti ti ẹ̀ṣẹ̀ tó ń fa ìsọdahoro ṣe máa pẹ́ tó,+ láti sọ ibi mímọ́ náà àti àwọn ọmọ ogun náà di ohun tí wọ́n ń tẹ̀ mọ́lẹ̀?”
13 “‘Bí mo ṣe ń wo ìran tí mo rí nígbà tí mo wà lórí ibùsùn mi, mo rí olùṣọ́ kan, ẹni mímọ́, tó ń sọ̀ kalẹ̀ láti ọ̀run.+
13 Mo gbọ́ tí ẹni mímọ́ kan ń sọ̀rọ̀, ẹni mímọ́ míì sì sọ fún ẹni tó ń sọ̀rọ̀ pé: “Báwo ni ìran ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nígbà gbogbo* àti ti ẹ̀ṣẹ̀ tó ń fa ìsọdahoro ṣe máa pẹ́ tó,+ láti sọ ibi mímọ́ náà àti àwọn ọmọ ogun náà di ohun tí wọ́n ń tẹ̀ mọ́lẹ̀?”