ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Dáníẹ́lì 4:13-16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 “‘Bí mo ṣe ń wo ìran tí mo rí nígbà tí mo wà lórí ibùsùn mi, mo rí olùṣọ́ kan, ẹni mímọ́, tó ń sọ̀ kalẹ̀ láti ọ̀run.+ 14 Ó ké jáde pé: “Ẹ gé igi náà lulẹ̀,+ ẹ gé àwọn ẹ̀ka rẹ̀ kúrò, ẹ gbọn àwọn ewé rẹ̀ dà nù, kí ẹ sì tú àwọn èso rẹ̀ ká! Kí àwọn ẹranko sá kúrò lábẹ́ rẹ̀, kí àwọn ẹyẹ sì kúrò lórí àwọn ẹ̀ka rẹ̀. 15 Àmọ́ ẹ fi kùkùté igi náà sílẹ̀ pẹ̀lú gbòǹgbò rẹ̀* nínú ilẹ̀, kí ẹ sì fi ọ̀já irin àti bàbà dè é láàárín koríko pápá. Ẹ jẹ́ kí ìrì ọ̀run sẹ̀ sí i, kí ìpín rẹ̀ sì wà pẹ̀lú àwọn ẹranko láàárín ewéko ayé.+ 16 Kí ọkàn rẹ̀ yí pa dà kúrò ní ti èèyàn, kí a sì fún un ní ọkàn ẹranko, kí ìgbà méje+ sì kọjá lórí rẹ̀.+

  • Lúùkù 21:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Wọ́n máa fi ojú idà ṣá wọn balẹ̀, wọ́n á sì kó wọn lẹ́rú lọ sí gbogbo orílẹ̀-èdè;+ àwọn orílẹ̀-èdè* sì máa tẹ Jerúsálẹ́mù mọ́lẹ̀, títí àkókò tí a yàn fún àwọn orílẹ̀-èdè* fi máa pé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́