-
Ẹ́kísódù 18:10, 11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Jẹ́tírò wá sọ pé: “Ẹ yin Jèhófà, ẹni tó gbà yín sílẹ̀ kúrò ní Íjíbítì àti lọ́wọ́ Fáráò, tó sì gba àwọn èèyàn náà kúrò lọ́wọ́ àwọn ará Íjíbítì. 11 Mo ti wá mọ̀ báyìí pé Jèhófà tóbi ju gbogbo ọlọ́run yòókù lọ+ torí ohun tó ṣe sí àwọn tí kò ka àwọn èèyàn rẹ̀ sí.”
-