Dáníẹ́lì 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bákan náà, ọba ní kí wọ́n máa fún wọn ní oúnjẹ lójoojúmọ́, lára oúnjẹ aládùn tí ọba ń jẹ àti lára wáìnì tó ń mu. Wọ́n máa fi ọdún mẹ́ta dá wọn lẹ́kọ̀ọ́,* tí ọdún náà bá sì ti pé, wọ́n máa bẹ̀rẹ̀ sí í bá ọba ṣiṣẹ́.
5 Bákan náà, ọba ní kí wọ́n máa fún wọn ní oúnjẹ lójoojúmọ́, lára oúnjẹ aládùn tí ọba ń jẹ àti lára wáìnì tó ń mu. Wọ́n máa fi ọdún mẹ́ta dá wọn lẹ́kọ̀ọ́,* tí ọdún náà bá sì ti pé, wọ́n máa bẹ̀rẹ̀ sí í bá ọba ṣiṣẹ́.