Dáníẹ́lì 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọba wá pàṣẹ fún Áṣípénásì olórí òṣìṣẹ́ ààfin rẹ̀ pé kó mú lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* wá, títí kan àwọn ọmọ ọba àti ọmọ àwọn èèyàn pàtàkì.+ Dáníẹ́lì 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn kan wà lára wọn tí wọ́n wá látinú ẹ̀yà* Júdà: Dáníẹ́lì,*+ Hananáyà,* Míṣáẹ́lì* àti Asaráyà.*+
3 Ọba wá pàṣẹ fún Áṣípénásì olórí òṣìṣẹ́ ààfin rẹ̀ pé kó mú lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì* wá, títí kan àwọn ọmọ ọba àti ọmọ àwọn èèyàn pàtàkì.+