ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sírà 8:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Lẹ́yìn náà, a fún àwọn baálẹ̀* ọba àti àwọn gómìnà agbègbè tó wà ní Ìkọjá Odò*+ ní ìwé àṣẹ ọba,+ wọ́n sì ti àwọn èèyàn náà àti ilé Ọlọ́run tòótọ́ lẹ́yìn.+

  • Ẹ́sítà 8:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Torí náà, wọ́n pe àwọn akọ̀wé ọba ní àkókò yẹn ní oṣù kẹta, ìyẹn oṣù Sífánì,* ní ọjọ́ kẹtàlélógún, wọ́n sì kọ gbogbo ohun tí Módékáì pa láṣẹ fún àwọn Júù àti fún àwọn baálẹ̀,+ fún àwọn gómìnà àti àwọn ìjòyè àwọn ìpínlẹ̀*+ tó wà ní Íńdíà títí dé Etiópíà, ìpínlẹ̀ mẹ́tàdínláàádóje (127), wọ́n kọ ọ́ sí ìpínlẹ̀* kọ̀ọ̀kan ní ọ̀nà ìgbàkọ̀wé tirẹ̀ àti sí àwùjọ èèyàn kọ̀ọ̀kan ní èdè tirẹ̀, bákan náà, wọ́n kọ ọ́ sí àwọn Júù ní ọ̀nà ìgbàkọ̀wé wọn àti ní èdè wọn.

  • Dáníẹ́lì 3:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Ọba Nebukadinésárì wá ránṣẹ́ sí àwọn baálẹ̀, àwọn aṣíwájú, àwọn gómìnà, àwọn agbani-nímọ̀ràn, àwọn olùtọ́jú ìṣúra, àwọn adájọ́, àwọn agbófinró àti gbogbo àwọn alábòójútó ìpínlẹ̀* pé kí wọ́n kóra jọ, kí wọ́n wá síbi ayẹyẹ tí wọ́n fẹ́ fi ṣí ère tí Ọba Nebukadinésárì gbé kalẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́