-
Dáníẹ́lì 2:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Lẹ́yìn náà, a ṣí àṣírí náà payá fún Dáníẹ́lì nínú ìran lóru.+ Dáníẹ́lì sì yin Ọlọ́run ọ̀run.