Dáníẹ́lì 8:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ní ti èmi, Dáníẹ́lì, okun tán nínú mi, ara mi ò sì yá fún ọjọ́ mélòó kan.+ Mo wá dìde, mo sì ń bá iṣẹ́ ọba lọ;+ àmọ́ ohun tí mo rí jẹ́ kí ara mi kú tipiri, kò sì sẹ́ni tó yé.+
27 Ní ti èmi, Dáníẹ́lì, okun tán nínú mi, ara mi ò sì yá fún ọjọ́ mélòó kan.+ Mo wá dìde, mo sì ń bá iṣẹ́ ọba lọ;+ àmọ́ ohun tí mo rí jẹ́ kí ara mi kú tipiri, kò sì sẹ́ni tó yé.+