Dáníẹ́lì 7:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “Mò ń wò ó bí ìwo yẹn ṣe bá àwọn ẹni mímọ́ jagun, ó sì ń borí wọn,+ 22 títí Ẹni Ọjọ́ Àtayébáyé+ fi dé, tí a sì dá àwọn ẹni mímọ́ ti Onípò Àjùlọ láre,+ àkókò tí a yàn pé kí àwọn ẹni mímọ́ gba ìjọba sì dé.+ Lúùkù 22:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 mo sì bá yín dá májẹ̀mú fún ìjọba kan, bí Baba mi ṣe bá mi dá májẹ̀mú,+
21 “Mò ń wò ó bí ìwo yẹn ṣe bá àwọn ẹni mímọ́ jagun, ó sì ń borí wọn,+ 22 títí Ẹni Ọjọ́ Àtayébáyé+ fi dé, tí a sì dá àwọn ẹni mímọ́ ti Onípò Àjùlọ láre,+ àkókò tí a yàn pé kí àwọn ẹni mímọ́ gba ìjọba sì dé.+