Dáníẹ́lì 10:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Mo wá láti jẹ́ kí o lóye ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí àwọn èèyàn rẹ ní àkókò òpin,+ torí ìran ohun tó ṣì máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú ni.”+ Dáníẹ́lì 12:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Ní tìrẹ, Dáníẹ́lì, ṣe àwọn ọ̀rọ̀ náà ní àṣírí, kí o sì gbé èdìdì lé ìwé náà títí di àkókò òpin.+ Ọ̀pọ̀ máa lọ káàkiri,* ìmọ̀ tòótọ́ sì máa pọ̀ yanturu.”+ Dáníẹ́lì 12:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó sì sọ pé: “Máa lọ, Dáníẹ́lì, torí pé ọ̀rọ̀ náà máa jẹ́ àṣírí, a sì máa gbé èdìdì lé e títí di àkókò òpin.+
14 Mo wá láti jẹ́ kí o lóye ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí àwọn èèyàn rẹ ní àkókò òpin,+ torí ìran ohun tó ṣì máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú ni.”+
4 “Ní tìrẹ, Dáníẹ́lì, ṣe àwọn ọ̀rọ̀ náà ní àṣírí, kí o sì gbé èdìdì lé ìwé náà títí di àkókò òpin.+ Ọ̀pọ̀ máa lọ káàkiri,* ìmọ̀ tòótọ́ sì máa pọ̀ yanturu.”+
9 Ó sì sọ pé: “Máa lọ, Dáníẹ́lì, torí pé ọ̀rọ̀ náà máa jẹ́ àṣírí, a sì máa gbé èdìdì lé e títí di àkókò òpin.+