Dáníẹ́lì 10:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Mo wá láti jẹ́ kí o lóye ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí àwọn èèyàn rẹ ní àkókò òpin,+ torí ìran ohun tó ṣì máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú ni.”+
14 Mo wá láti jẹ́ kí o lóye ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí àwọn èèyàn rẹ ní àkókò òpin,+ torí ìran ohun tó ṣì máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú ni.”+