Dáníẹ́lì 6:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nǹkan wá túbọ̀ dáa fún Dáníẹ́lì yìí nínú ìjọba Dáríúsì+ àti nínú ìjọba Kírúsì ará Páṣíà.+ Dáníẹ́lì 11:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Ní tèmi, ní ọdún kìíní Dáríúsì+ ará Mídíà, mo dìde láti fún un lókun, kí n sì fún un lágbára.*