Dáníẹ́lì 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ní ọdún kẹta àkóso Ọba Bẹliṣásárì,+ èmi Dáníẹ́lì rí ìran kan, lẹ́yìn èyí tí mo kọ́kọ́ rí.+