Ìfihàn 19:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Bákan náà, àwọn ọmọ ogun ọ̀run ń tẹ̀ lé e lórí àwọn ẹṣin funfun, wọ́n wọ aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa,* tó funfun, tó sì mọ́ tónítóní.
14 Bákan náà, àwọn ọmọ ogun ọ̀run ń tẹ̀ lé e lórí àwọn ẹṣin funfun, wọ́n wọ aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa,* tó funfun, tó sì mọ́ tónítóní.