-
Dáníẹ́lì 7:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 “Òpin ọ̀rọ̀ náà nìyí. Ní ti èmi, Dáníẹ́lì, èrò ọkàn mi dẹ́rù bà mí gan-an, débi pé ara mi funfun;* àmọ́ mo fi ọ̀rọ̀ náà pa mọ́ sínú ọkàn mi.”
-