-
Dáníẹ́lì 2:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Inú wá bí ọba gidigidi, ó sì pàṣẹ pé kí wọ́n pa gbogbo amòye Bábílónì run.+
-
-
Dáníẹ́lì 2:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ìgbà yẹn ni Dáníẹ́lì rọra fọgbọ́n bá Áríókù tó jẹ́ olórí ẹ̀ṣọ́ ọba sọ̀rọ̀, òun ló jáde lọ láti pa àwọn amòye Bábílónì.
-